omo ila orangun JÉ ÀGBÉ KALÈ LÁTI OWÓ " Adélówòtán Tolúwanimí Adékóláwolé '' FÚN GBÍGBÉ "ÈDÈ, ÀSÀ ATI ÌSE'' ÌLÚ WA GA .PÈLÚ MÍMÚ ÌGBÉGA BÁ ÌLÁ ÒRÀNGÚN ÀTI ÀGBÉGBE RÈ NÍPA FÍFI ÌSÈLÈ TÍ ÓHÚN SELÈ LÓWÓLÓWÓ JÁDE HÀN WÁ PÈLÚ FÍFI ÀWON OHUN ÀBÁLÁYÉ WA HÀN WA NÍLÈYÍ ÀTI LÓKÈ ÒKUN . ÀWON OHUN WÒNYÍ NI ÀWON ÀKÀNSE ISÉ WA GBOGBO BI" OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN ,,,,,, All Old Student Of Ila Grammar School, Ila Orangun,,,,, IGBONNIBI OLD STUDENT ASSOCIATION. NIBIANS,,,,,AGBOLUAJE GRAMMAR SCHOOL, ILA ORANGUN,,,,, COLLEGE HIGH SCHOOL, ILA ORANGUN,,,,, Ajagunnla Grammar School, Ila Orangun,,,,,Isedo High School, Ila Orangun,,,,, ILÉ ÈRÁN ÌLÁ ÒRÀNGÚN,,,,, TABI ÈTÒ SÓ LE MEDÈ ÌLÁ WI ". ÌLÁ ÒRÀNGÚN KÒLÈ BÀJÉ O. +234833962037, BBM-3278B430.About Us
              
OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN JE ETO TI AGBE KALE FUN GBOGBO OMO BIBI ILU ILA ORANGUN LATI MON NIPA OHUN GBOGBO AWON ILOSIWAJU TI OHUN LO NINU ILU ILA ORANGUN PAPAJULO NIPA 'ASA ATI ISE WA'. EYI KI SE FUN OLOSELU TABI OLOJELU RARA, BIKOSE TI AWON OLUFE ATI OLUFERAN ILOSIWAJU ILU WA. GEGE BI ASE MON WIPE ÌLÁ ÒRÀNGÚN NI OLORI GBOGBO AWON IGBOMINA TI O WA JAKE JADO ILE YORUBA NI ILU "NIGERIA" EDI NIYI TI A SE FE KI GBOGBO WA JO WO ONA TI A LE GBA LATI GBE OGO ILU ÌLÁ ÒRÀNGÚN GA ATI LATI SO DI EYI TI YIO DI MI MON FUN GBOGBO AGBAYE GEGE OJULOWO OMO BIBI ÌLÁ ÒRÀNGÚN LATI MO OJUSE WA TI O YE LATI SE FUN IDAGBASOKE ILUWA YI. PAPA JULO LATI LE GBE EDE ILU WA GA ATI LATI SO DI MI MO FUN GBOGBO AGBAYE GEGE BI EDE 'GEESI' SE GBAJUMO TO. BAKANNA NI AFE KI IREPO ATI IFE JOBA LARIN AWA OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN NI'LE, LOKO ATI LEHIN ODI PELU AWON ARA OKE-OKUN BAKANNA. ILA EE NI BAJE O. EEEEKUN O.


More Information

EYI NI LATI SO FUN GBOGBO OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN WIPE ILU WA YI NIFE YIN TI O SI HUN ROWA WIPE KI E JOWO KI E WA SI'LE LATI WA DA ILE-ISE HUNLA HUNLA SILE NITORI YORUBA BO WON NI ' ILE NI ABO SINMI OKO O'. MOSI GBADURA WIPE  LAGBARA OLORUN OBA OGA OGO GBOGBO WA NI A MA KERE OKO WA DELE LASE EDUMARE.

   Contact UsEmail:
ADELOWOTAN BUILDING,
ILE-ERAN, OKE-EDE.
ILA ORANGUN, OSUN STATE.
NIGERIA.
 
Bbm:- 3278B430
Email:- adelowotankola@gmail.com 

AWON IROYIN LEREFE NIPA ILU ILA-ORANGUN NIYI.

EKUN O GBOGBO OMO EGBE NINU ILE YI O, EKU POPOSINSIN OPIN OSE TUNTUN IHO. EDAKUN SISE AWON AFIHAN ELEGBEJEGBE YI KII SE WIPE AKAN NFI SE IFIHAN LASAN BI KOSE WIPE AUN SO FUN WA LATI DARAPO MO ELEYI TI O BA JE TI WA NINU AWON ILE-IWE YI TI O WA NINU ILU ILA ORANGUN LATI LE FI KO ARAWAJO PAPAPO FUN GBIGBEGA ILE-IWE WA. PAPAJULO LATI LE SE AWARI ARAWA FUN IGBA ATIJO TI AJIJO WA NI ILE IWA NA. ILA ORANGUN KONI BAJE O, ILE-IWE TI ENIKOOKAN WA NA TI JADE KONI GBEYIN LAWUJO BEENI KONI DOHUN IGBAGBE LARI ILU O. AMIN. " Igbonnibi HS Ila-orangun , Ila Grammar ,Agboluaje Grammar-school , Ila-Orangun College-High , Ajagunnla Grammar-School Ila Orangun , Isedo HighSchool-Ila . Isedo High School, Ila Orangun , Ajagunnla Grammar School, Ila Orangun , AGBOLUAJE GRAMMAR SCHOOL, ILA ORANGUN "

FUN EYI KEYI IBEERE TI EBA NI FUN IDAGBA SOKE AWON EGBE YI, E LE KOWE SI WA LORI WEBSITE WA TABI KI E PE OLOOTU SI ORI ERO LAGBEKA YI +2348188015425 www.omoilaorangun.com/ . GBOGBO WA YIO KERE OKO DELE LAYO O, EDAKU EMO GBAGBE ILE O, NITORI ILE NI ABO SIMIN OKO. IREE O.

ILA ORANGUN CITY ANTHEM

1. Ni ILU ILA ORANGUN
Nibe ni a ti gbe bi mi.
Ni ilu ti AJAGUNNLA te
Omo bibi ODUDUWA
Akoni to koko joba 
OBA ILU ORANGUN NI 
ILU to loba to tutu
Nibe ni ati gbe bami.

2. Nilu Ila Orangun
Nibe la gbe temi dagba 
Ilu OBA IGBONNIBI tun te
Ila ilu ominira
Emi o filu Ila sogo
ORANGUN lolori IGBOMINA
Ilu to lora to tutu
Nibe la gbe tomidagba

3. Eyin Omo Ila Orangun
Ejeki ki awa sowopo
Lati tun ilu wa se
Ila ilu olokiki
Eje ka gbe Ila leke
Ka wa filu Ila sogo
Eje ki a wa sowopo 
Lati tun ilu wa se 

4. Ilu Ila ori oke 
Ilu ibukun Oluwa 
K'oluwa se l'oni bukun
Eho, eyo ke si gberin
Ogo f'olorun wa 'lorun
Ila ilu Ori oke 
Ilu ibukun Oluwa
K'oluwa se loni bukun. Loruko gbogbo omo egbe OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN jake jado agbaye papajulo lori ero ayelujara yi.Emi ogbeni Adelowotan Adelowotan Toluwanimi Adekola , Iya-afin Fatimon Elemede Yusuff Ibrahim , Ayeni Adelani Prince , fi asiko yi ki '' Oba Olukayode Oyedotun Bibire I " fun ayajo odun kewa ati ti isile AFIN-OBA tuntun eleyi ti yoo bere lati ojo kejile-logun titi ojo kerinle-logun osu karun ti awa yi 22-24/05/2013. Aki babiyesi wipe ki Ade pe lori, ki Bata pe lese, ki Irukere ki o di okinni, igba tiyin ti eun lo lowolowo yi ki ilu Ila-Orangun ki o ma roju siwaju si, ki o si ma toro lo bee, oun otun-otun ki o ma je tiwa ni Ilu wa gegebi bi eni poruko omo OYEDOTUN, Iwa pele pele ati omoluabi ki o ma gbe wa wo bi ewu, bi eni yangan bi BIBIRE-AKOKO nitori bi a ba bini seni atun ara eni bi. Kabiyesi oooo, gbogbo awa omo ILA ORANGUN yika otun beeni atun yi tosi foba alade tiun gbadobale oba. Ekun oo, eku aseye o, igba odun, kii mon je odun kan fun yin o. Ase wa.
Ope pataki fun awon egbe eleyi ti aunpe ni "ILA ACTION COUNCIL /Ajagunnla Day" ati awon egbe miran ti a kole daruko wipe eseun fun iranlowo ati isapa yin lati le jeki ajodun eleyi na jasi ayo ati idunnu. Gbogbo awa omo Ila ni ekun o, eku ise na Eledua ee jeki gbogbo aa kere oko dele o. Ase wa www.omoilaorangun.com +2348095084520, +2348033962037.


‎                                                         IROYIN ELENUKAN 
                 ILA TIHUN DARA BOWA O, EJEKI A FI ARA BA’LE KI A SI GBA WIPE O TI DARA DE TAN O.
a. KI LODE O?
b. KINI A RI O?
c. TABI KINI AGBO O?

1. KI LODE O? :- Gegebi a se mo wipe opolopo oju tuntun ti a koriri ni ilu ILA-ORANGUN ni opolopo wa se alabapade won ninu odun ti o koja lo yi ti se odun 2012. Ti eleyi si jasi wipe ohun otun tihun lawabo sipo ni ila-orangun, papa julo awon omo wa ti won wasile odun ni odun yi ti won koti wa sile ri rara sugbon ti OLORUN ti segi OLA ati OLA fun lawoju fun abewo akoko.

2. KINI A RI O? :- Ohun ti oyani lenu julo ni wipe opolopo ninu awon ti won wa sile odun yi kode ile ri ti opolopo kosi da AGBOLE tabi EBI won mo Kankan mo rara fun idi-kan tabi ekeji sugbon, ti won ko gbo iroyin gidi Kankan lenu awon obi won tabi ara won ti won johun gbe ni ilu okere ti won ngbe tabi ti won wa. Sugbon, fun iyalenu awon ohun ti won foju ri kaakakiri ilu ti o si je idunu fun won ti won ko ni ni ero gegebi awon ohun ti awon obi won ko so fun won nitori wipe awon gangan ko ti pada wale lati bi odun die ti won ti wale gbeyi bi INA, AWON OPOPONA OLODA TUNTUN TI O DARA, pelupelu awon AGBEGBE TUNTUN ti o wa ni ayika wa ti awon eniyan Nla Nla nfi ile kiko dani ARA ni awon adugbo ti akolero bayi ti awon IYA ati BABA won gangan ko tile le ni lero nipa re rara nitori wipe o ti pe ti awon Obi won ti kuro ni ILE. Sugbon, fun idi eyi inu opolopo won ndun fun ise itesiwaju ti o de bawa lati owo awon IJOBA WA, OBA WA, AWON ENIYAN NLA NLA TI ANI NI ILU-ILA-ORANGUN nse lati le mu ILU-ILA-ORANGUN goke agba. Eyi lomu ki awon ODO ati awon AGBA wonyi na gbiyan lati ra ile fun ile-gbigbe ati fun ile-ise kiko nitori awon ohun ti won nri yi bi INA ati AWON OJU ONA KOOKAN ati ile Nla Nla ti won nba pade ni awon agbegbe ti won nlo kaakiri ilu ILA ORANGUN. 

3. KINI AHUN GBO? :- Hun, Yoruba BO won wipe “INU DUNDUN LO MAHUN MU ORIYA” Eyi lomu ki awon eniyan ti won ni ile fun ILE-ISE tele sugbon fun idikan tabi ekeji won ni lati fa si eyin sugbon ni akoko yi ti won ti ri wipe iyipada ti de ba ohun gbogbo ni ilu wa lomu ki won fe bere si se ise lori awon ile won bayi lori dida ile-ise won na sile ti yio si se ahunfani fun emi ati eyin pelu awon omo wa ti ohun bo leyi wa ola. 
FUN IRANLOWO ATI ATILEYIN OKAN NINU AWON OLUDA ISE SILE YI :- Ahun fi asiko yi be ALAGA ATI GBOGBO AWON IGBIMO papajulo awon ti won wa nipa eto titun ojuona se ati igbimo so igbe digboro ti ILA ORANGUN LOCAL GOVERNMENT COUNCIL. Wipe ki won jowo bawa wa atunse si ojuona kan ni ti ahunpe ni “IGBO ILEKE STREET” agbegbe “COL. ADENIJI HOUSE”. Awon eniyan yi sowipe awon ti setan lati gbe ile-ise won wa lati ilu-eko bi oju-ona na bale di sise ti awon yio si bere ise nibe kiakia ki awon miran le fi ti won se awokose rere. Sugbon ohunkan ti ohun dawon duro yin na ni ONA yi, ESE PUPO, ILA KONI BAJE O.

IKINI KU ISE KOLE DARA:- LORUKO GBOGBO ILE GEGEBI ETI RANMI WIPE, AWA omo ila orangun NILE YI ATI LOKE-OKUN NI OHUN KI “ Oba Olukayode Oyedotun Bibire I Awotunde Olusegun Victor , GBOGBO OSISEIla Local Govt , Jide Ezekiel Adeniji , Bisi Akande , GBOGBO IJOYE ILU ILA PATAPATA, PELU GBOGBO AWON BABA BABAWA NLA NLA TI WON GBE OGO ILU ILA GA PELU AWON IYAWA GBOGBO TI WON NSE ISE TAKUNTAKUN LORI KI O LE DARA FUN ILA-ORANGUN. AKI YIN WIPE E SE PUPO, ILE ATI ONA YIN NA KONI DARU O. EJOWO EJEKI A BAWA WA ATUNSE SI OJU-ONA TI ASO NIPA RE YI O FUN AHUNFANI TI O TI DETAN NIBE. “ILA-ORANGUN KONI BAJE O”. [ASE O] +2348188015425 Adelowotan Toluwanimi Adekola

“ omo ila orangun“ IDUPE ATI IKINNI FUN ODUN TI O KOJA ATI ODUN TUNTUN

LORUKO EMI Adelowotan Toluwanimi Adekola, ATI GBOGBO AWON OLUDARI MI PATAPATA LORI GBOGBO ETO EGBE “ Omo Ìlá Òràngún“ YI NFI ASIKO YI KII GBOGBO ILE WIPE AKU ODUN ASIKU ASEKU ODUN TUNTUNTI 2013 WIPE EMI WA YIO SE PUPO RE LAYE ATI LA’YE WA O (AMIN). BAKANNA NI MO SI FI ASIKO YI KI GBOGBO EYIN ENI BI ENI, ENIYAN BI ENIYAN TI OLORUN NLO PATAPATA LORI ETO YII FUN IRANLOWO ADURA YIN LORI WA , PELU IRANLOWO MIRAN LONAKAN TABI EKEJI, SUGBON TI E KO FE KIA DA ORUKO YIN LORI AFEFE NI ILE YI TABI NI OKE-OKUN, LATI IGBATI ATIDA EGBE YIN SILE NI NKAN BI ODUN MERIN SEYIN WA NI ORI ERO AYELUJARA YI. MO NDUPE GIDIGIDI FUN ATILEYIN YIN GAN NIO. 

MOGBANI ADURA WIPE WIPE GBOGBO ADAWOLE YIN NINU ODUN TUNTUN YI YIO YORI SI RERE LOLA OLUWA, OKO KII ROKO AIBOWALE, BEENI ADA KII ROKO AIPADA WASIL, GBOGBO OWOO TI ADA ATI OKO BASE NI WON NKERE RE WASILE NIGBA IKORE. MO WA LO GBOLOHUN YI FUN YIN LONI WIPE, EMI ATI EYIN O KERE OKO DELE LAYO ATI ALAFIA, GBOGBO IGBATI O BA SIHUN DUN FUN YIN LAYE , ESU KONI DA EMI ENIKOKAN WA LORI ETO “OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN “ YI NI EGBODO LOLA ELEDUMARE (AMIN). 

MOHAN KI YIN WIPE ESEUN LOPOLOPO, AJAGUNNLA EE GBE GBOGBO AA PAPO O, ILA ORANGUN EE HAN NI BAJE TITI LAELAE LASE EDUMARE. OMO ILA ORANGUN MOHUN KIYIN OOOOO, EEEKUN OOOO. Ila-Orangun LG boss harps on cleanliness
Written by Monday, 03 September 2012
The Executive Secretary, Ila Local Government Area of Osun State,
ChiefAwotunde Olusegun Victor, has advocated promotion of sanitation, hygiene and clean environment in the state as an effective tool to reduce mortality.
According to Awotunde, while speaking with Community News in Ila-Orangun during the last environmental sanitation exercise organised by the state government, said one third of the global burden of diseases could be attributed to negative environmental factors such as polluted air, dirty water, poor sanitation and insect transmitted diseases among others.
His words, "The current problems facing the environment are vast and diverse which made me to applaud our amiable governor, Mr Rauf Aregbesola, for introducing a monthly cleaning exercise for the residents of the state to be tidying and cleaning their various communities in order to avert epidemic diseases".
The council boss further urged the people of the state to inculcate the habit of tree planting and recycling in order to control global warming.
Also speaking with Community News during the exercise, the Orangun of Ila, Oba Wahab Oyedotun Bibire, commended residents of the community for trooping out en-mass to observe the exercise.
The Orangun further admonished his people to always make sure that their surroundings were clean, while the drainage must be free for stream to pass, saying these steps would prevent any future flood disaster
.

Hun, bi aba sise ire ah KU, bi aba si sise buruku laye IKU na ni yio gbeyin enikokan wa nile aye. Gbogbo ile fi asiko yi ki eyin ebi okan ninu wa idile FAYOYIN wipe ao ni ri iru iku odo bayi larin yi ati larin wa mo o, mosi feki elomon wipe ewe knkan koni jabo leyin OLUWA laipe oluwa mi mon si, ki ejowo ki e je kagba fun OLORUN OBA wipe , INALILAHI WAHINA LIROJUINAH. Fayoyin Segun Adewale SUN RE O.http://www.facebook.com/fayusadewale?ref=ts

Aibawon sinibe ni aibawon dasi. Bi o tile je wipe oti lo sinmi laya Jesu sugbon emi re si wa laye. Emi na fi asiko yi ki baba mi http://www.facebook.com/cheif.adeosun?ref=ts ku ayajo odun awon babawa kakiri agbaye OLOYE CHIEF EJIO OF ILA ORANGUN, CHIEF EJIO OF IFE OYEE LADE, ENGR. ADELOWOTAN OYEWOLE ADEOSUN ku odun. Mo si hunfi asiko yi kan na se iranti won wipe MOFE WON SUGBON JESU FE WON JU MI LO, "BABA IFE, ABI'LA ALADE, SOBORO AMEYIN JOBINRIN, OMO ADESHI OHUNPO LEWU, OMO ADESHI TEMI SERI ADE, MIE BA TERI ENIWA, ADESHI DUDU LEGBON, PUPA LABURU WON NILE ADELO'DE, OLOORO MI OMO EPO, ENI ADESHI BASUN YIE LOYUN AH JEWI OMO LOTAN NINU OLUWA RE NI .HUN, IKU EE MON ENI AMULERU, ARUN EE MON ENI AH DE NIGBEKU. BABA TOLUWANIMI AKOLAWOLE OKO IYAFIN Adelowotan Aya-Ejio SUN RE O. Baba ni babami , babami baba ti moni ...........................!

Loruko emi OLOOTU ati awon OLUDARI mi ni Adu’pe Pataki lowo OLORUN ELEDUMARE pelu gbogbo eyin baba wa, iya wa, egbon wa, ati aburo wa lokunrin ati lobinrin laiyo enikan Kankan sile wipe EKUN O, Ehan ku ijo meji ‘jometa kan o. Mo hun fi asiko yi ki gbogbo ile wipe ESEUN  eku ife yin lori awon ETO wa gbogbo fun atileyin yin ati ifowo sowopo yin lori gbogbo ohun ti ahunse. Bakanna atihun dupe lowo gbogbo eyin eni bi eni, eniyan bi eniyan ti ohun PE  wa lori ERO ayelujare tabi ko LETA ranse siwa fun ti OJO’BI ti OLOOTU ogbeni ADELOWOTAN TOLUWANIMI ADEKOLA ati ti ODUN IDASILE eto OMO ILA ORANGUN yi kanna ti o pe odun META seyin bayi wipe ESEUN o adupe lowo yin gan ni o. Asi gba ni adura wipe OLORUN koni pa ina IFE ti a ni fun ara  wa o {AMIN}. Ese pupo o, Loruko OLUWA, Ila Orangun koni baje laelae lola ELEDUMARE.           +2348188515425 

EYI NI ABAJADE GBOGBO IPADE TI ATIHUNSE LORI ILE IWE WA TI IGBONNIBI HIGH SCHOOL,  ILA ORANGUN.


 Bayi ni abeere ipade na pelu adura lati enu Alhaji Jamiyu Jubril ti won je alaga  gbogbo ipade na ti Iya-afin Shehu T.L. na sije igbakeji alaga  gbogbo ipade ti a se patapata .

 

Leyin eyi ni Ogbeni Ayobami Morufu Alabi ka abajade ipade ti o koja si gbogbo ile lati mo ohun bi ipade na se lo sit a. Leyin na ni Ogbeni Adelowotan Adekola Toluwanimi A.K.A. Omo Ila Orangun na ka gbogbo oro ti awon eniyan ti oje omo ile-iwe Igbonnibi High School so jade lori Ero Ayelujara ti Facebook  si gbogbo ipade lati lemo ohun ti ohun lo nipa oro ile iwe wa yi. Ti inu gbogbo omo egbe si dun si gbogbo oro ti a ka jade yi ti opolopo si ri oruko awon eniyan ti won jo keko jade ti o wa lori facebook yi wipe awon oro awon gangan ni awon eniyan yi.

 

Bakanna ni opolopo awon akoko jade sihun so orisirisi itan larin ara wa nipa igba ti ada ile-iwe yi sile. Ninu awon oro wonyi bakanna  ni ABA ti o di OFIN lati se ayajo akoko ti ada ile iwe wa yi sile fun iranti ti waye.

 

Bi ako ba gbagbe wipe ada ile-iwe yi sile ni Odun  1976  sugbon OFFICIAL DATE re si je January 3RD 1977. Ni eyi ti o jasi wipe ni ojo keta osu kinni  January 3RD odun 2013 ni agbodo se aye dida ile-iwe wa yi sile ti yio sipe Odun merin-le-logoji 26year. Ti gbogbo ile si fowo si ti won si wipe ki abeere sini kede re fun gbogbo akeko jade ninu ile-iwe wa lati asiko yi lo lori ero ayelujara ati awon akegbe wa gbogbo ti a bamo ni arowoto wa.

 

Nipa sise eleyi pelu opolopo awon Akanse eto lori ifilole NIBIANS ajodun yi yio tun mu ilosiwaju ba ile-iwe yi fun awon ogo ti ohunbo wa pelu  Ilu ILA ORANGUN lati le ni idagba soke ju bi o ti walo larin ara wa fun awo kose awon ILE-IWE miran fun awokose rere yi. Gbogbo wa ni amo bi oruko IGBONNIBI yi se je Ila Orangun ni Pataki julo larin awon ojulowo omo bibi ODUDUWA patapata fun idi eyi ni a fi fe ki irepo ati ife beere lati ilu ile-iwe wa lo lati asiko yi fun igbaga tabi igbedide ilu ILA ORANGUN.  Awon akanse eto yi a fun wa ni opolopo ahunfani lati le gburo awon ORE wa ti o tipe ati lati lo ahunfani yi lati ipnile ohun rere tuntun lele larin arawa ati ilu wa.

 

Leyin opolopo ijiroro lolokan o jokan ni apari gbogbo ipade na ni ojo isinmi  ti Ogbeni Ayobami Morufu A.K.A. Ilalonpe pelu Ogbeni Adelowotan Adekola Toluwanimi A.K.A. OMO ILA ORANGUN si dupe lowo gbogbo ile fun wiwa sibi ipade ati fifi asiko won sile fun gbogbo eto olojo meji ti ase yi, bakanna ni won sai dupe lowo gbogbo awon ti won wa lati ona jinjin bi, Abuja, Ilorin, P-Hourt, Ondo, Abeokuta, Lagos State fun wipe won bawa pejopo fun igba akoko ati fun emi iferan ti won fe fun ile-iwe wa lati fi ohun ti won se sile lati wa fun ipejopo yi ti won si se adura wipe ki OLORUN ki o bawa sowon pada dele layo.

 

Bayi ni apari ti Iya Afin Shehu T.L. si gbadura ipari ni ojo isin yi . Ti won si gbawa niyanju bakan na wipe ki ajowo so fun awon eniyan wa nibi gbogbo nipa awon ohun ti o je aba jade ipade na ati wipe ki won mase gbagbe ipade ti ohunbo ti yio si waye ni ojo ti yio pari Osu yi 30TH Of June 2012.

 

Eyi ni gbogbo abajade ipade na o, Ese pupo.

 

Fun Ibeere lori ohun ti o bar u yin loju, ejowo e le pea won won yi :-

(1.) OBAWALE ADEBISI 08035321993

(2.) BARR. SEGUN DUROTOLU 08079000906

(3.) MORUFU ALABI AYOBAMI 07073328101

(4.) ADELOWOTAN ADEKOLA MOSES 08033962037

(5.) MRS. Shehu T.L. a.ka. EYE ori ODAN .


http://omoogboye.org/ 2. http://www.ilaunityassociation.org/photos.html 3. http://ilaelementsociety-uk.com/userimages/forum.htm 4. www.omoilaorangun.com/ 

Eyi ni amoran mi fun awa odo ila orangun lati so fun wa wipe ibowo fun agba nihun je ki ari unkan agba gba! fun idi eyi mo fe ki fi towo towo se agbe yewo awon 'website' ero aye lujara yi fun ohun ti ani lati mon nipa bi awon eniyan se ni ife ara ilu si fun orisirisi iranlowo ati ahunfani ti ohunbe ninu awon eto kookan ti won gbe kanle fun eni ti o ba le se iwadi re daada ati nipa ohun biribiri daradara ti won ti gbe se ni ilu ila nitori kii se ori FACEBOOK nikan lati le mon sugbon agbodo ni ife imon toyekoro ati oye daada siwaju si nipa won nitori ojo iwaju nitori ahi bawon sinibe ni won mahun ni aibawon dashi, eni ti o ba si beere ni ahun fii fun. nitori abeere kii sii ona o, ki ejeki afi ara baale wo awon ''website'' yi finni finni ki abale mon ahunfani ti a le ko nipa ninu re ni o. Adura mi ni wipe olorun yio ma so agbara gbogbo awon egbe yi di otun lase edumare. loruko oluwa ise ibi koni de ba enikan kan ninu gbogbo wa pelu awa omo egbe na jake dado gbogbo agbaye. oke, oke ni ilu ila orangun yio ma lo loruko OLUWA. Amin

My best regards to every member of omo ila orangun;for us to embark on this great assignment of bringing unity amongst us in the interest of developing our dear town, there are some misdeed that has been done or still operational either ignorantly or intentionally by some people that has sown seed of discord in the community that has retarded the developmental process of our town which we need to first address as a sign of readiness for new things to spring forth. Views from members will serve as pointer to the root of the problem facing us as a community thereby directing us to a path to tread for sustainable growth of ila orangun. ADELOWOTAN TOLUWANIMI ADEKOLAWOLE +2348033962037.

MO FE KI EYIN OJOGBON OMO BIBI ILA ORANGUN SE AGBEYEWO ORO YI LATI ENU OJOGBON " OYEWOLE SIKIRU" FUN AHUNFANI LATI SE ATUNSE NIBI TI ORO NA BA TI TABA WA NI ETI ASO TABI NI OJU ARA, OLORUN YI O MA FUN WA SE O. AMIN

Mo ki olotu ore mi adelowotan toluwanimi adekolawole ku ise ribiribi yi olorun yio wa pelu e .Mo ki gbogbo omo ila nile loko ati leyin odi wii a dara fun gbogbo wa o o . Pataki oro mi da lori ibere ti e bere wipe nje ilosiwaju ti e n ba ila ? A ni fe ara ha ni ila. bere lati odo awon olori pelu awon baba baba ti won ti lo oba ni ijoye ni omowe ni ati awa ta je omo ilu pelu ara .Kabere ni ati ibi oselu se ila nikan ni won ti hun se oselu nile karo ojire ni ? To wajewipe boba o pa bo ba o bulese lawa hun ba kakiri ni odun1999_ 2003 Akande wole gomina nipile osun adibo loto sugbon omo ila wa larin awon to hun lu ilu kowo kowo fun baba ti ko fi wole ekeji mo ni 2003 .Awon oloselu wa si ila won wa se iforowero won gbe ero ibaniso fun omisore oro to jade lenu okunrin naa ni ojo na ni pe ha ila le . Itumo oro na ko ye mi. EGBO KINI ITUMO ORO YI. Ni odun ti won hun pin ijoba ibile nigbati won da ipinle osun sile tan Ti wo so oruko ijoba ibile naa ni oke ola local gov omo ila loyi pada si okeila local gov. se ila kere lati ni ijoba ibile meji melo lo wa ni ile ife ilesha osogbo ede.Awon to je asoju wa ninu oselu ti won ba ti de oke tan won ti gbagbe ero isale .Amo wipe ani ina monamona sugbon se owulo fun wa .Sebi ani damu omi ero ni ila se omi kari toba yo ni isedo ko ni de okejigbo beletasi wi ede oke ola ati oke ede.Ati egbo ninu itan wi ila ni han ti re te ikirun do to baribe se bi ila seri ni ikirun ri. Oropo nibe sugbon kolorun yan awon eyan rere ti ha.( ejowo ejeka ma ka akole dada kato ma da si oro. Mo tun fi akoko yi pe awon to hun gbe aworan sori ayelu jara won yi eje ka ma gbe ohun ti awon eniyan yio ri ti won o mo wipe ilu rere lati wa han omo ila níkakò ni wo huka ee se ila orangun eni daru .a o ni rogun lase Edumare.


Ekun o gbogbo eyin Odo lokunrin ati lobinrin ninu ile yin o, eyin ni lati so fun yin wipe eto ti aso wipe yio bere laipe yi lori ero aye lujara lati inu egbe omo ila orangun ti a pe ni "SÓ LE MEDÈ ÌLÁ WI" gegebi oruko egbe tabi eto yi, aho bere si ni mu wa si imuse lagbara OLORUN ti asi ni igbagbo wipe e o bawa gba gegebi ati pe oruko re be wipe SÓ LE MEDÈ ÌLÁ WI nitoripe ede ila tabi ede yoruba nikan ni o le ni ahunfani lati dasi eto na nitori awa odo ti ohun wa OKO ati AYA tabi awa ti afe se ATUNYAN IYAWO LEYIN ODUN DIE TI AYA TABI OKO TI FI WA SILE ti o si wuwa lati fe omo bibi ilu wa ti hunse OMO ILA ORANGUN. Fun idi eyi ejowo a fe ifowo sowopo yin wipe ki ejowo bawa fi awon ohunti ahunpe ni iriri yin lado ore kunrin ati ore binrin yin lati eyin wa sowo si OGBENI Omo Ìlá Òràngún tabi Adelowotan Toluwanimi Adekola , TABI ki e fiwe sowo siwa lati oriwww.omoilaorangun.com/ tabi ki e pe olootu si ori ero agbagbe yi +2348033962037, ki awon omo iya wa miran maba kose nibi ti awa ni ti kose nigba kan ri. Asi fi asiko yi bewa lokunrin ati lobinrin wipe ki a ma se tiju bi enikan ba wuwa lori eto yi ki a jowo so fun olootu fun awon eto ti o ye ki o ma ba si ipalara rara. ILA ORANGUN YIO GBEWA O. ESE PUPO. +2348033962037 http://www.facebook.com/groups/197364433688522/ NOTE:- Ejowo aye wa fun eni ti o ba fe se itumo oro yi lowo ara re fun gbogbo ile, nitori ki o ma ba si ibeefun itumo oro yi nitorina ara ohun ti eto yi wafun ni gbigbe ewa ede ile awon baba wa ga bi awon oloyinbo se gbe ede GEESI won ga ju lagbaye . ire oooooo 


OBA ADETONA WILLIAMS Hun, bi a ba ranti iku akoni se laafi ida lale gaaragaa. Iran emon nikan niku yi oju opo re mon di, Iran alakan ni ku yi isa han mon di koto. Bi eni bi eni eyan bi eyan ba rorun are mabo, ise rere iwa rere, oruko rere han ee dibaje nile alaye. Lodifa fun ojo kini ana ti ti oba wa waja OBA AYENI oye momo yeni OGUN sun re o. Ahun mu asiko i se ranti han loni yi o di Odun ketala '13 years ago' yi baba a waja yi gbogbo ILA ORANGUN se iranti han loni. Lotito baba ah ku amo o sun ni o, nitori baba ah fi opolopo omo ati omo omo sile saye lo pelulu ORUKO RERE yi ehan ni baje lailai. Mo ki gbogbo omo ila orangun wipe aku iranti ojo oni o. Omo ila orangun ni ohun kede fun gbogbo ile ati gbogbo awon ebi won. Ire ooooo.  Oba oninu ire.       02/05/1999-02/05/2012.   


EJOWO FUN IRANLOWO OHUN TI ABA NI LATI RAN OMO IYA WA LOWO GEGEBI OMO LAKEJI WA ATI ENI TI O NIFE ILU ILA ORANGUN PELUPELU ENI TI O NIFE 'OBA WILLIAM ADETONA AYENI TO REWALE ASA NI OJO KINNI ANA 02/05/1999. EYI NI BI IBEERE FUN IRANLOWO NA SE LO. ...............LATI OWO OGBENI ...........Adegoke Ademola............SI GBOGBO ILE .........
Eekun o gbogbo eyin omo Ila ni tile toko, ha e ko ere oko dele o. Ikan pataki ninu ihan yi nsere ori itage ati sinima Yoruba ni mi. Mo si je ikan lara ihan omo Oba Williams Adetona Ayeni ti o waja. Ki Kabiesi to ku, Baba so ITAN ILA ORANGUN bi erisi merin fun mi ni ojo ti mo ko gbogbo ihan omo egbe osere ti han wa labe mi lati Eko lo si ILA, Baba sure fun gbogbo ha. Ikan ninu itan yi ni mo ti se ni ori Itage ni NATIONAL ARTS THEATRE IGANMU, LAGOS ni odun 1998. Akole itan naa ni OGUN PAYABAYABA ti o je itan bi Kabiesi ati Omo Oba ADEBAYO se du oye ORANGUN fun odun meje 1960-1967 ki oto ja mo Baba lowo titi ti OGUN PAYABAYABA se sele ni odun 1969. Mo polowo itan yi gidi gan ti inu hall kun ni emeteta ti a se ere naa 12,3&6 pm. Ni bayi mo fe se itan yi si SINIMA AYE ODE ONI, lati mo fi se iranti OBA ADETONA AYENI fun ise ribiribi ati iyipada nla ti o de ba ILU ILA ni asiko ti Baba fi je OBA lori ILA ORANGUN. Mo ti se sinima ti o po die seyin, sugbon ahan itan ILA ORANGUN yi mofe mo se yi je eyi ti e na mi lowo gan nitori CULTURE/MODERN ati PURE CULTURE ni o je. FUN IDI EYI A FE IRANLOWO LATI OWO GBOGBO EYIN OMO ILA ORANGUN TI OFE IGBELEKE ILU ILA ORANGUN, FUN ALAYE NI KIKUN ATI IBEERE EPE MI SI ORI ERO IBANISORO YI +2348088376271, +2348032241104

According Mr. Folorunso Sikiru Akintunde "says" If u are an Ila indigene and you a university graduate wt B.Sc or B.Tech in Building Technology,Quantity Surveying and Estate Management (with or without M.Sc.). Pls contact me on 08034658608 or 08057732816. Tanx  May God bless you for the good news. ......................E LE DARAPO MO WA LORI AWON ETO YIN Omo Ìlá Òràngún TABI omo ila orangun ,OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN , SÓ LE MEDÈ ÌLÁ WI KAKIRI AGBAYE. ESE PUPO.

EYIN NI LATI SO FUN EYIN OMO IYA MI WIPE AHUNFANI KAN TI SI SILE FUN GBOGBO ENI TI O BAHUN WA ISE NI ILE ISE IFOWOBAMO "BANK JOB" FI ASIKO YI SOFUN YIN WIPE ILE ISE G.T.BANK FE GBA OGUNLOGO AWON ENIYAN SI ILE ISE WON PELU IWE ERI TI O YANRANTI GEGEBI ASE KA SILE YI.........2:2 FROM ANY DISCIPLINE, 5 CREDITS AT WAEC/NECO INCLUDING MATHS AND ENGLISH PELU OJO ORI TI KO KOJA ODUN METADIN LOGBON SI ISALE. KI WON SI FI IWE-ERI WON NA SOWO SI APOWE YI ........ haruna.musa@gtbank.com/ . TI GBOGBO WA KONI SORO SE LASE EDUMARE. IRE OOOOOOOO. +2348033962037.. 

Eyin ni oro lati enu babami Clement Akanni si awa Omo Ìlá Òràngún wipe ................ A QUALIFIED ENGINEER INTENDING TO BE DIRECTOR OF WORKS OR AN AUDITOR CAPABLE OF HEADING AUDIT DEPT OF A PARASTATAL UNDER THE STATE GOVT SHOULD GET IN TOUCH IMMEDIATELY. THIS WALL POST IS FOR ILA INDIGENE ONLY, PLS. THANK U


NIGERIA INCORPORATED ELECTRONICS PRATISIONAL ILA-ORANGUN CHARPER .
AFI ASIKO YI KI GBOGBO AWON TI AFIWEPE TI WON WA TABI TI WON RANSE SIWA BI Oba Olukayode Oyedotun Bibire I,Awotunde Olusegun Victor , OLOOTU EGBE omo ila orangun PELU IGBAKEJI ALAGA KANSUU ILA, ATI GBOGBO AWON TI AKOLE DARUKO. FUN AJODUN OLODODUN PELU IKOWOJO FUN ILE EGBE WA TI A SE NI OJO SATIDE TI O KOJA YI 21/04/2012 NI ABE ALAGBA WA N.I.E.P. TI EKA TI ILA ORANGUN LAPAPO.

1. ALH. RAIMI KOLAWOLE ( ALIAS BOYS FOR LIFE). "ALAGA EGBE"
2.ENGR. OLADAPO MUDASIRU "AKOWE EGBE"
3. ALFA ABDUL AZEEZ ARIYO "AKA'PO EGBE"
4. ENGR. S.O. OJO & OLUSINA OLAYIWOLA "TI AWON MEJEJI JE OLUDARI GBOGBO AYEYE GBOGBO"

EJOWO, ASI TUN FI ASIKO YI BEBE LOWO GBOGBO OMO ILA ORANGUN NILE LOKO FUN IRANLOWO TI OLUKALUKU WA BALE SE FUN EGBE YI LORI ILE KIKO WA TI O WA NI TOSI " ILA ORANGUN LOCAL GOVERMENT SECRETARIAT, OKE OSIN ILA. ILOSIWAJU ATI KOLE DARA FUN TOLORI TELEMU ILU ILA PATAPATA NI EGBE YI WA FUN NI ILU AJAGUNLA TIWA O. AGBADURA WIPE OLORUN YIO KO ILE AYO NA FUN GBOGBO WA O. ILU ILA ORANGUN KO SI NI BAJE LAELAE. ASE O

Ejowo ahunbere fun awon igbimo fun old ila gram school wipe ki won jowo ko iwe-eri si olootu tabi ki won ma se se ibinu nitoripe awon eto kan wa ti afe mase laipe yi lori eto ti o le jemo gbigbe ile iwe re larunge ni awon ojo kookan ti ale ya si oto ni ori eto yi gegebi awon eniyan sehun beere sugbon awon aseyori yi Fe ajoropapo awon igbimo ile-iwe kookan ti ani ni ila-orangun papajulo won yio won inu ori website wa lo bi ajoropapo ti o gba muse bawa. E se pupo. Ebi wa koni baje o, besini idi- temi adelowotan adekola omo baba ejio of ila-orangun na o ni baje ni Ile-Eran loke-ede. Iree o. Omo Ìlá Òràngún +2348033962037

EJOWO EGBE YI FE IRANLOWO YIN KI AWON ETO TI WON NI LOKAN KI O LE WA SI IMUSE. OHUN KOHUN TI EBA NI LAGBARA LATI FI RAN EGBE YI LOWO KI EJOWO KI JEKI AMON TABI KI E BAWA FI SI IKAN NINU AWON ILE-ISE IFOWOPAMO "BANK" KAN NINU AWON TI A DARUKO WON YI  . E SE PUPO OLORUN YIO MA RAN GBOGBO WA LOWO O. AMIN

ADELOWOTAN ADEKOLA MOSES 
FIRST BANK OF NIGERIA, 
IWO-ROAD BRANCH,
ACCT NO. 4353010022377
       
 OR
                                   
ADELOWOTAN ADEKOLA MOSES 
GURANTY TRUST BANK, 
OFFA BRANCH, 
ACCT NO. 471486376190
 

The inaguration of various committees of ILA ACTION COUNCIL were successful. The turn out was quiet encouraging. The committees are: commerce & industry, infrastuctural development, youth & sport dev., tourism, employment and agric & agro-allied. (Education, health and media comm had been previously inagurated).All these committees need the support and encouragement of all indigens and lovers of ila orangun to achieve meaningfully. All for the progress of ila. Ila a dara, Ajagunla a gbe wa. Name:
Phone:
Email:
Message:

About Us

OMO ÌLÁ ÒRÀNGÚN JÉ ÈTÒ TI AGBÉ KALÈ LÁTI OWÓ "ÒGBÉNI ADÉLÓWÒTÁN ADÉKÓLÁ TOLÚWANIMÍ MOSES'' FÚN GBOGBO ÀWÁ OMO BÍBÍ ÌLÚ ÌLÁ ÒRÀNGÚN FÚN GBÍGBÉ "ÈDÈ, ÀSÀ ATI ÌSE'' WA GA. ÀTÍ WÍPÉ AFÉ KÍ OKÁN WA FÀ SÍ ILÈ BABA WA ÀTÍ ÒDÈDÈ TÍ WÓN TI BÍWA FÚN ÌLOSÍWÁJÚ ÀTI ÌRÀNLÓWÓ ARAWA TÀBÍ FÚN ALÁÌNÍ. KÍ ÌLOSÍWÁJÚ LE BÁ ÌLÁ ÒRÀNGÚN JÙ BÁYÌ LO. ''ÌLÁ È LÒGÙN, EMU LÒGÙN ÌLÁ'' . ÌLÁ È NÌ BÀJÉ, EMÒ KÚN O .

Contact Us

  • ADELOWOTAN BUILDING, ILE-ERAN COMPOUND, OKE-EDE .
    SUITE 5, OKUNOLA SHOPPING COMPLEX, BESIDE CAPITAL HOTEL, OSOGBO
    ILA ORANGUN, Osun 23406
    Nigeria

WORLDWIDE